Mat 27:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu si duro niwaju Bãlẹ: Bãlẹ si bi i lẽre, wipe, Iwọ ha li Ọba awọn Ju? Jesu si wi fun u pe, Iwọ wi i.

Mat 27

Mat 27:2-21