Mat 26:58 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Peteru tọ̀ ọ lẹhin li òkere titi fi de agbala olori alufa, o bọ́ si ile, o si bá awọn ọmọ-ọdọ na joko lati ri opin rẹ̀.

Mat 26

Mat 26:57-65