Mat 26:40 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si tọ̀ awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ wá, o bá wọn, nwọn nsùn, o si wi fun Peteru pe, Kinla, ẹnyin ko le bá mi ṣọ́na ni wakati kan?

Mat 26

Mat 26:32-45