Mat 26:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Peteru wi fun u pe, Bi o tilẹ di ati ba ọ kú, emi kò jẹ sẹ́ ọ. Gẹgẹ bẹ̃ni gbogbo awọn ọmọ-ẹhin wi pẹlu.

Mat 26

Mat 26:33-36