Mat 24:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni nwọn o fi nyin funni lati jẹ ni ìya, nwọn o si pa nyin: a o si korira nyin lọdọ gbogbo orilẹ-ède nitori orukọ mi.

Mat 24

Mat 24:8-11