Mat 22:38-41 Yorùbá Bibeli (YCE) Eyi li ekini ati ofin nla. Ekeji si dabi rẹ̀, Iwọ fẹ ọmọnikeji rẹ bi ara rẹ. Ninu awọn ofin mejeji yi ni