Mat 2:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wipe, Dide, mu ọmọ-ọwọ na, ati iya rẹ̀, ki o si lọ si ilẹ Israeli: nitori awọn ti nwá ẹmí ọmọ-ọwọ na lati pa ti kú.

Mat 2

Mat 2:10-22