Mat 19:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Peteru dahùn, o si wi fun u pe, Wò o, awa ti fi gbogbo rẹ̀ silẹ, awa si ntọ̀ ọ lẹhin; njẹ kili awa o ha ni?

Mat 19

Mat 19:22-30