Mat 16:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi ó si fun ọ ni kọkọrọ ijọba ọrun: ohunkohun ti iwọ ba dè li aiye, a o si dè e li ọrun: ohunkohun ti iwọ ba tú li aiye, a o si tú u li ọrun.

Mat 16

Mat 16:10-25