Mat 12:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ẹnyin iba mọ̀ ohun ti eyi jẹ: Anu li emi nfẹ ki iṣe ẹbọ; ẹnyin kì ba ti dá awọn alailẹṣẹ lẹbi.

Mat 12

Mat 12:2-12