Mat 12:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tabi ẹnyin ko ti kà a ninu ofin, bi o ti ṣe pe lọjọ isimi awọn alufa ti o wà ni tẹmpili mbà ọjọ isimi jẹ ti nwọn si wà li aijẹbi?

Mat 12

Mat 12:1-12