Mat 12:44 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni o wipe, Emi o pada lọ si ile mi, nibiti mo gbé ti jade wá; nigbati o si de, o bá a, o ṣofo, a gbá a mọ́, a si ṣe e li ọṣọ.

Mat 12

Mat 12:35-50