Mat 12:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn o dahùn o si wi fun wọn pe, Iran buburu ati iran panṣaga nwá àmi; kò si àmi ti a o fi fun u, bikoṣe àmi Jona wolĩ.

Mat 12

Mat 12:38-40