Mat 12:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin ọmọ paramọlẹ, ẹnyin ti iṣe enia buburu yio ti ṣe le sọ̀rọ rere? nitori ninu ọ̀pọlọpọ ohun inu li ẹnu isọ.

Mat 12

Mat 12:28-38