Mat 12:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tabi ẹnikan yio ti ṣe wọ̀ ile alagbara lọ, ki o si kó o li ẹrù, bikoṣepe o kọ́ dè alagbara na? nigbana ni yio si kó o ni ile.

Mat 12

Mat 12:28-39