Mat 12:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati awọn Farisi gbọ́, nwọn wipe, Ọkunrin yi kò lé awọn ẹmi èṣu jade, bikoṣe nipa Beelsebubu, olori awọn ẹmi èṣu.

Mat 12

Mat 12:23-32