Mat 12:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wo iranṣẹ mi, ẹniti mo yàn; ayanfẹ mi, ẹniti inu mi dùn si gidigidi: Emi o fi ẹmí mi fun u, yio si fi idajọ hàn fun awọn keferi.

Mat 12

Mat 12:8-28