Mat 11:13-16 Yorùbá Bibeli (YCE)

13. Nitori gbogbo awọn wolĩ ati ofin li o wi tẹlẹ ki Johanu ki o to de.

14. Bi ẹnyin o ba gbà a, eyi ni Elijah ti mbọ̀ wá.

15. Ẹniti o ba li etí lati fi gbọ́, ki o gbọ́.

16. Ṣugbọn kili emi iba fi iran yi wé? O dabi awọn ọmọ kekeke ti njoko li ọjà ti nwọn si nkọ si awọn ẹgbẹ wọn,

Mat 11