Mat 1:10-12 Yorùbá Bibeli (YCE)

10. Hesekiah si bí Manasse; Manasse si bí Amoni; Amoni si bí Josiah;

11. Josiah si bí Jekoniah ati awọn arakunrin rẹ̀, nigba ikolọ si Babiloni.

12. Lẹhin ikolọ si Babiloni ni Jekoniah bí Sealtieli; Sealtieli si bí Serubabeli;

Mat 1