Mat 1:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. IWE iran Jesu Kristi, ọmọ Dafidi ọmọ Abrahamu.

2. Abrahamu bí Isaaki; Isaaki si bí Jakọbu; Jakọbu si bí Juda ati awọn arakunrin rẹ̀;

3. Juda si bí Faresi ati Sara ti Tamari; Faresi si bí Esromu; Esromu si bí Aramu;

Mat 1