Mak 9:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lojukanna baba ọmọ na kigbe li ohùn rara, o si fi omije wipe, Oluwa, mo gbagbọ́; ràn aigbagbọ́ mi lọwọ.

Mak 9

Mak 9:16-28