Mak 9:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si da wọn lohùn, o si wipe, Iran alaigbagbọ́ yi, emi o ti ba nyin gbé pẹ to? emi o si ti mu sũru fun nyin pẹ to? ẹ mu u wá sọdọ mi.

Mak 9

Mak 9:9-26