Mak 8:9-11 Yorùbá Bibeli (YCE)

9. Awọn ti o jẹ ẹ to ìwọn ẹgbãji enia: o si rán wọn lọ.

10. Lojukanna, o si wọ̀ ọkọ̀ pẹlu awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀, o si wá si apa ìha Dalmanuta.

11. Awọn Farisi si jade wá, nwọn bẹrẹ si bi i lẽre, nwọn nfẹ àmi lati ọrun wá lọwọ rẹ̀, nwọn ndán a wò.

Mak 8