Mak 8:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

LI ọjọ wọnni nigbati ijọ enia pọ̀ gidigidi, ti nwọn ko si li onjẹ, Jesu pè awọn ọmọ-ẹhin rẹ sọdọ rẹ̀, o si wi fun wọn pe,

Mak 8

Mak 8:1-8