Mak 7:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si paṣẹ fun wọn pe, ki nwọn ki o máṣe sọ fun ẹnikẹni: ṣugbọn bi o ti npaṣẹ fun wọn to, bẹ̃ ni nwọn si nkokikí rẹ̀ to;

Mak 7

Mak 7:27-37