Mak 7:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mu u kuro larin ijọ enia lọ si apakan, o si tẹ ika rẹ̀ bọ̀ ọ li etí, nigbati o tutọ́, o si fi ọwọ́ tọ́ ọ li ahọn;

Mak 7

Mak 7:32-36