Mak 7:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori obinrin kan, ẹniti ọmọbinrin rẹ̀ kekere li ẹmi aimọ́ gburo rẹ̀, o wá, o si wolẹ lẹba ẹsẹ rẹ̀:

Mak 7

Mak 7:23-32