Mak 7:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ẹnyin wipe, Bi enia ba wi fun baba tabi iya rẹ̀ pe, ohunkohun ti iwọ iba fi jère lara mi, Korbani ni, eyini ni Ẹbùn, o bọ́.

Mak 7

Mak 7:5-20