Mak 6:55 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si sare lọ si gbogbo igberiko yiká, nwọn bẹ̀rẹ si ima gbé awọn ti ara wọn ṣe alaida wá lori akete, si ibiti nwọn gbọ́ pe o wà.

Mak 6

Mak 6:51-56