Mak 6:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si gbé ori rẹ̀ wá ninu awopọkọ, o si fi fun ọmọbinrin na: ọmọbinrin na si fi fun iya rẹ̀.

Mak 6

Mak 6:22-37