Mak 6:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lojukanna, o si wọle tọ̀ ọba wá kánkan, o bère, wipe, emi nfẹ ki iwọ ki o fi ori Johanu Baptisti fun mi ninu awopọkọ nisisiyi.

Mak 6

Mak 6:17-26