Mak 6:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ọjọ ti o wọ̀ si de, ti Herodu sàse ọjọ ibí rẹ̀ fun awọn ijoye rẹ̀, awọn balogun, ati awọn olori ni Galili;

Mak 6

Mak 6:13-23