Mak 6:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si lé ọ̀pọ awọn ẹmi èṣu jade, nwọn si fi oróro kùn ọ̀pọ awọn ti ara wọn ṣe alaida, nwọn si mu wọn larada.

Mak 6

Mak 6:12-17