Mak 5:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lọgan Jesu si ti mọ̀ ninu ara rẹ̀ pe, aṣẹ ti ara on jade, o yipada larin ọpọ enia, o si wipe, Tali o fi ọwọ́ kàn mi li aṣọ?

Mak 5

Mak 5:28-33