Mak 5:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NWỌN si wá si apa keji okun ni ilẹ awọn ara Gadara.

2. Nigbati o si ti inu ọkọ̀ jade, lojukanna ọkunrin kan ti o li ẹmi aimọ pade rẹ̀, o nti ibi ibojì jade wá,

3. Ẹniti o ni ibugbe rẹ̀ ninu ibojì; kò si si ẹniti o le dè e, kò si, kì iṣe ẹ̀wọn:

Mak 5