Mak 4:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

On pãpã si wà ni idi ọkọ̀, o nsùn lori irọri: nwọn si jí i, nwọn si wi fun u pe, Olukọni, iwọ ko bikita bi awa ṣegbé?

Mak 4

Mak 4:30-40