Mak 4:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ilẹ a ma so eso jade fun ara rẹ̀; ekini ẽhù, lẹhinna ipẹ́, lẹhinna ikunmọ ọkà ninu ipẹ́.

Mak 4

Mak 4:27-29