Mak 3:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun wọn pe, O tọ́ lati mã ṣe rere li ọjọ isimi, tabi lati mã ṣe buburu? lati gbà ẹmí là, tabi lati pa a run? nwọn si dakẹ.

Mak 3

Mak 3:1-9