Mak 3:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati awọn ẹmi aimọ́, nigbàkugba ti nwọn ba ri i, nwọn a wolẹ niwaju rẹ̀, nwọn a kigbe soke, wipe, Iwọ li Ọmọ Ọlọrun.

Mak 3

Mak 3:10-18