Mak 15:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ti nrekọja lọ si nfi i ṣe ẹlẹyà, nwọn si nmì ori wọn, wipe, A, Iwọ ti o wó tẹmpili, ti o si kọ́ ọ ni ijọ mẹta,

Mak 15

Mak 15:28-37