Mak 15:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pilatu si bi i lẽre, wipe Iwọ ha li Ọba awọn Ju? O si dahùn wi fun u pe, Iwọ wi i.

Mak 15

Mak 15:1-8