Mak 14:62 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu si wipe, Emi ni: ẹnyin o si ri Ọmọ-enia joko li ọwọ́ ọtún agbara, yio si ma ti inu awọsanma ọrun wá.

Mak 14

Mak 14:58-69