Mak 14:60 Yorùbá Bibeli (YCE)

Olori alufa si dide duro larin, o si bi Jesu lẽre, wipe, Iwọ kò dahùn kan? kili eyi ti awọn wọnyi njẹri si ọ?

Mak 14

Mak 14:57-64