Mak 14:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Jesu wipe, Ẹ jọwọ rẹ̀ si; ẽṣe ti ẹnyin fi mba a wi? iṣẹ rere li o ṣe si mì lara.

Mak 14

Mak 14:4-14