Mak 14:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ mã ṣọna, kì ẹ si mã gbadura, ki ẹ má ba bọ́ sinu idẹwò. Lõtọ li ẹmí nfẹ, ṣugbọn o ṣe ailera fun ara.

Mak 14

Mak 14:34-44