Mak 14:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si lọ siwaju diẹ, o si dojubolẹ, o si gbadura pe, bi o ba le ṣe, ki wakati na le kọja kuro lori rẹ̀.

Mak 14

Mak 14:29-45