Mak 14:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mu Peteru ati Jakọbu ati Johanu pẹlu rẹ̀, ẹnu si bẹrẹ si yà a gidigidi, o si bẹré si rẹ̀wẹsi.

Mak 14

Mak 14:25-42