Mak 14:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ si jade lọ, nwọn wá si ilu, nwọn si ri i gẹgẹ bi o ti sọ fun wọn: nwọn si pèse irekọja silẹ.

Mak 14

Mak 14:11-17