Mak 13:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori awọn eke Kristi, ati awọn eke woli yio dide, nwọn o si fi àmi ati ohun iyanu hàn, tobẹ̃ bi o ṣe iṣe, nwọn iba tàn awọn ayanfẹ pãpã.

Mak 13

Mak 13:17-24