Mak 12:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ kili oluwa ọgba ajara na yio ṣe? On o wá, yio si pa awọn oluṣọgba wọnni run, yio si fi ọgba ajara rẹ̀ ṣe agbatọju fun awọn ẹlomiran.

Mak 12

Mak 12:7-12